August 23, 2019
Politics

INEC Kede Atundi Ibo Lawon Ipinle Kan

Ajo Eleto Idibo, INEC ti kede pe ohun yo seto idibo Gomina ati tile Asofin lawon ipinle mejidinlogun ti idibo won o fenuko sibi kan lola ode yi.

Oga agba eleto idibo, Ogbeni Festus Okoye lo soro yi di mimo nilu Abuja.

Amosa o tun wa kede ojo keji ati ikarun osu kerin fun kikede idibo ipinle Rivers.

Iyabo Adebisi/Kemi Ogunkola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *