October 18, 2019
Home Archive by category Yoruba

Yoruba

Yoruba
Ìpàdé lórí ẹ̀kún owó osù oní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n tí ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ àti ìjọba gùùnlé ni ó tún ti forí sọ́pọ́n nígbàtí wọ́n ò lee fẹnu kò síbi kan lẹ́yìn wákàtí mẹ́san tí wọ́n ti ńsèpàdé. Alákoso fọ́rọ̀ àwọn òsìsẹ́ àti ìgbanisísẹ́, Dókítà Chris Ngige nígbàtí ó n bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ nílu Abuja […]Continue Reading
Yoruba
Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ilẹ̀ yíì Sẹ́nátọ̀ Ahmed Lawan, sopé orílẹ̀èdè Náijírìa nílò àdúrà kólè boorí àwọn ìpèníjà rẹ̀. Sẹ́nátọ̀ Lawan sọ èyí nígbà tó ńgba àwọn asòfin tójẹ́ ọmọ lẹ́yìn Krístì lálejò. Ẹgbẹ́ àwọn asòfin tó jẹ́ ọmọ lẹ́yìn Krítì ọ̀hún ní igbákejì adarí ilé Sẹ́nátọ̀ Ovie ọmọ-Agege àti akójanu ilé Sẹ́nátọ̀ Orji […]Continue Reading
Yoruba
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde sọpé ètò ìsèjọba tóun ńléwájú rẹ̀ kóní tẹ̀tì láti gùnlé àwọn ìpinnu èyí tí yóò fẹsẹ̀ ìdàgbàsókè tóò lórin múlẹ̀ nípinlẹ̀ Ọyọ. Ó sọ èyí nígbà tó ńgba àbọ̀ ìwádi ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni méje, èyítí ìsèjọba rẹ̀ gbé kalẹ̀ láti wòye sí oníruru ìpèníjà tó ńkojú ìpínlẹ̀ yíì, lọ́fìsì […]Continue Reading
Yoruba
Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé, kòní pẹ́ tó n yóò fi sàgbéyẹ̀wò owó osù gbogbo àwọn tó dipò òsèlú mú pátá. Ìlú Abuja lalákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́, ọ̀mọ̀wé Chris Ngige ti sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì, lákokò àbẹ̀wò ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ láwọn ìjọba ìbílẹ̀. Gẹ́gẹ́ bó se wípé, ó sepàtàkì kíwọ́n sàgbéyẹ̀wò owó osù àtàwọn […]Continue Reading
Yoruba
Alákoso fọ́rọ̀ ohun àlùmọ́nì inú omi, onímọ̀ẹ̀rọ Suleiman Adamu, ló ń fẹ́ káwọn ọmọdé kásà bééyan se fọwọ́ lóre kóre pẹ̀lú ọsẹ àtomi, látidpenà ọ̀kan ọ̀jọ̀kan àrùn. Omímọ̀ẹ̀rọ Adamu tó sàlàyé pé pàtàkì ọwọ̀ fífọ̀, rọ àwọn alágbàtọ́ láti kásà ìmọ́tótó fi dábòbò àwọn ọmọdé kúrò lọ́wọ́ àwọn àrùn lọ́lọ́kan òjọ̀kan. Kò sài sọ́ọ́di mímọ̀ […]Continue Reading
Yoruba
Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ asòfin, Sẹ́nátọ̀ Ahmed Lawan ti kéde pé, gbogbo àwọn ilé-isẹ́ àti lájọlájọ,  gbọ́dọ̀ wa farahàn níwájú ilé láti wá sọ̀rọ̀ gbe àbá ètò ìsúná wọn lẹ́yìn, títí ọjọ́ kọkọ̀ndínlọ́gbọ̀n osù yíì. Asòfin Lawan sọpé, ìgbésẹ̀ yíì ló wáyé níbamu pẹ̀lú bí wọ́n se ka àbá ètò ìsúná ọdún 2020 fún igbákejì nílé […]Continue Reading
Yoruba
Ìdúnadúrà tó ń wáyé láarin ìjọba àpapọ̀ àtẹgbẹ́ òsìsẹ́ lórí ọ̀rọ̀ owó osù àwọn òsìsẹ́ tókéré jùlọtún bẹ̀rẹ̀ lóni nílu Abuja. Ìpàdé náà tí wọn ò forí rẹ̀ tìsíbìkan lána niwọ́n tún gùnlé ní dédé ago méjì ọ̀sán òní. Igbákejì àarẹ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Amaechi Asugunim, fi ìrètí hàn pe, ìpàdé náà yóò […]Continue Reading
Yoruba
Iléésẹ́ asọ́bodè nílẹ̀ yíì, ti kéde fífòfinde láinigbèdéke lórí kíkó ọjà wọlé tàbì fífi ọjà sọwọ́ sílẹ̀ òkèrè láti ẹnu bodè ilẹ̀ yíì. Ọga-àgbà fúnleesẹ́ as abodè, Ọ̀gágun Fẹ̀yìntì Hameed Ali, ẹni tó sọ̀rọ̀ yíì níbi ìpàdé àwọn oníròyìn tówáyé nílu Abuja, sọpé ilé olómìnìra Niger náà ti fòfinde kíkó ìrẹsì wọlé láti ilẹ̀ náà […]Continue Reading
Yoruba
Alákoso fétò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè àwọn agbègbè, ọ̀gbìn Sabo Nanono sọpé, ilẹ̀ Nàijírìa ńpèsè óunjẹ́ tootoo, láti bọ́ àwọn èèyàn rẹ̀, tí yóò sìtún ma kólọ sáwọn orílẹ̀dè alámulégbé rẹ̀. Alákoso náà sọ̀rọ̀ yíì nígbà tó ńbá àwọn oníròyìn sọ̀rs nílu Abuja, lórí àyájọ́ óunjẹ lágbayé. Ó fikun pé ìjọba àpapọ̀ ti pinu láti ti […]Continue Reading
Yoruba
Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ yíì àti ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ńfikùnlukùn láti fọ̀rọ̀jomito ọ̀rọ̀, lórí àlékún owó osù òsìsẹ́ tówà lákàsọ̀ tókéréjù ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n náirà. Ìpàdé yíì ló ń wáyé lẹ́yìn ìpàdé èyí tíwọ́n se lána òdeyi níbi tẹ́gbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ti fi ìpinu wọn lórí àlékún náà hàn, tí ìpàdé òní sì níse pẹ̀lú ìpinu […]Continue Reading
Load More