Yoruba

Àjọ elétò ìdìbò fi aráalu lọ́kàn balẹ̀ lórí ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yíì,INEC, sọpé mìmì kankan kòní mì ètò ìdìbò sí ipò Àarẹ láifi ti iná ọmọ rara tó bá àwọn ẹ̀rọ asayẹ̀wò cárdi oludìbò kan jẹ.

Alága àjọ INEC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu, sọ èyí di mímọ̀ nígbà tó sèfilọ́lẹ̀ ibùdó kan táwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ ọmọnìyàn yóò ti máà tọpinpin ètò ìdìbò.

Ọga àgbà àjọ INEC, ọ̀hún ẹnití ọ̀kan lára àwọn alákoso ẹgbẹ́ náà, ọ̀gbẹ́ni Fẹstus Okoje sojufún níbi ètò ìlanilọ́yẹ̀ tọ́kasi pé, iná tó jó mẹ́ta nínú àwọn ilésẹ́ INEC, níll yíì ti fa ìfàsẹ́yìn sí ètò tíwọ́n tise sílẹ̀ fún ìgbáradì tó gúnmọ́.

Ẹwẹ, ọ̀jọ̀gbọ́n Yakub sàlàyé pé, ìfàsẹ́yìn náà kòní mákùdé bá ètò ìdìbò gbangban-làsáta, pẹ̀lú àlàyé pé, ilésẹ́ shún ti sètò min fi wójùtú sí àwọn ẹ̀rọ asayẹ̀wò cárdi oludòbò tó bájẹ.

Ó wá fikun ọ̀rọ rẹ̀ pé, àjọ INEC, kòní yẹ ọjọ́ ìdìbò labẹ́ àkóso bótuwù kórí.

Ogunkọla/Adebis

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *