Yoruba

Ilé Asòfin Ìpínlẹ̀ Ọyọ ní adarí tuntun

Wọ́n ti kéde ọ̀gbẹ́ni Debọ Ogundoyin, gẹ́gẹ́bí adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ, késan-an.

Asòfin Ade Babajide tó sojú ẹkùn ìdìbò àríwá Ìbàdàn kejì ló kọ́kọ́ dábáà pé, kí yan ọ̀gbẹ́ni Ogundoyin, gẹ́gẹ́bí adarí ilé asòfin ti wọn fi lọ́ lẹ̀ lóni na, lẹ́yìn na ni ọ̀gbẹ́ni Adeola Bamidele kín-in lẹ́yìn.

Bákanà ni wọn ti yan ọ̀gbẹ́ni Abiodun Fadeyi tó ń sojú ẹkùn ìdìbò Ọnaara, gẹ́gkbí igbákejì adarí ilé asòfin na.

Ogunkọla/Kehinde

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *