Ìjọba Àpapọ̀ tí ro àwọn ìgbìmò tuntun tájo tó ń rísí ìgbéléwọn okoowo nílè yí láti ṣíṣe wọn, pẹ̀lú ìfọkànton, àkóyawo àti gbangba lásán tá láti lè jẹ́ káwọn oludokowo nílè ókéré ní ìgbọ́kànlé láti lè wá ṣíṣe nílè yí.

Akọwe àgbà, lájo tó ń rísí ètò ìṣúna, Alhaji Mohmoud ìṣà-Dutse ló soro yi, lásìkò tí wọ́n ṣe ifilole ìgbìmò Aláṣẹ òhun nílu Abuja.

Pẹ̀lú àlàyé pé ifilole ìgbìmò titun náà ló ń wáyé lásìkò tó lapere, tó sì ṣàlàyé pé àjọ náà gbọ́dọ̀ sise láti jé káwọn oludokowo lagbokanle nínú ètò ọ̀rọ̀ ajé nílè yi.

Ìgbìmò tuntun eléni mẹsan, náà ló jẹ́ pé àwọn márùn ń sise fáwọn àkókò díẹ̀, nígbà tí àwọn mẹ́rin tooku n sise ní gbogbo gbà.

Alága ìgbìmò òhun ni, ogbéni Olufemi Lijadu, arábìnrin Mary Uduk ni ódele fún ogagba àjọ òhun.

Kémì Ogunkola/Lara Ayoade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *