News

Àarẹ Buhari yóò kéde àwọn alákoso lósù tó ǹbọ̀

Ìkéde àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ alásẹ ààrẹ Muhamadu Buhari tí ọ̀pọ̀ ti ńfojú sọ́nà fún ni yóò wáyé lósù tó ńbọ̀, yi lẹ́yìntí ilé asòfin àgbà bá ti se ohun gbogbo tó yẹ tí wọ́n sì padà lẹ́yìn ìsinmi.

Akọ̀wé ìjọba ilẹ̀ yi Boss Mustapha tó kéde eléyi nígbà tó ńbá àwọn akọròyìn sọ̀rọ̀.

Ọgbẹni Mustapha sọ pé, ààrẹ yóò gbé orúkọ náà síwájú ilé asòfin fún àyẹ̀wò àti ìgbàwọlé láì fàkókò sòfò rárá.

Kẹmi Ogunkọla/Sherif

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *