News

Gómìnà Fayẹmi pèfún ìfọ́wọsowọ́pọ̀ láti kojú ìsòro àabò

Ọmọwe Kayọde Fayẹmi ti pè fún ìfọ́wọsowọ́pọ̀ lẹ́kajẹ̀ka láti kojú ìsòro ọ̀rọ̀ ààbò tó ńbá orílẹ̀èdè yi fínra.

Ọmọwe Fayẹmi sọ̀rọ̀ yi níbi ìsíde ìpàdé kan tó dá lórí ọ̀rọ̀ ààbò nílu Ado Ekiti.

Gómìnà Fayẹmi tó tún jẹ́ alága ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà sọ pé, ìfọ́wọsowọ́pọ̀ àwọn elétò ààbò, Ọba alayé, dórí agbègbè àti olórí ẹ̀sìn láti gbógunti ìsòro ààbò àti ìwa ọ̀daràn.

Kẹmi Ogunkọla/Olulana

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *