Gẹ́gẹ́ bí àayan rẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀ka ètò ìlera lọ́dọ̀ rẹ̀, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti ń pín ẹ̀rọ òpó ìbára ẹni sọ̀rọ̀ lọ́nà ìgbàlóde àgbèléwò ta mọ̀ sí Tablets àti Adroid Phones, fáwọn òsìsẹ́ alábojútó àti olùtọpinpin lábẹ́ àjọ tó ńbójútó ọ̀rọ̀ àwọn ilé ìwòsàn àti láwọn ìjọba ìbílẹ̀ gbogbo tó wà nípinlẹ̀ náà.

Gẹ́gẹ́ bí àlàyé látọ̀dọ̀ alákoso ètò ìlera nípinlẹ̀ Òndó, Dókítà Wahab Adegbenro, tó pín àwọn èròjà ìsisẹ́ náà níbi ìdánilẹ́kọ fáwọn tọ́rọ̀ kan, fi kálàlé rẹ̀ pe, ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti ní àkọsílẹ̀ tó pójúowó nípa ètò ìlera lọ́dọ̀ rẹ̀ ni.

Dókítà Adegbenro tún sọ wípí, ìgbésẹ̀ náà yóò tubọ̀ jẹ́ kí àkọsílẹ̀ nípa àmọ́jútó ètò ìlera nípinlẹ̀ náà fẹ́sl múlẹ̀ si fún ìrọ̀rùn aráalu nípasẹ̀ òpó ayélujára.

Ogunkọla/Tọba

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *