News

Gómìnà Akeredolu sèlérí láti lo owó ìjọba ìbílẹ̀ bótitọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òndó, ọ̀gbẹ́ni Rotimi Akeredolu sọ pé ìpínlẹ̀ náà ò ní tẹ̀tì láti máà lo owó ìjọba ìbílẹ̀ bótitọ́ àti bótiyẹ.

Ìlú Àkúrẹ́ ni Gómìnà Akeredolu tó sọ̀rọ̀ yi níbi ìbúra fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ méjìdínlógún tí wọ́n fi sí ìjọba ìbílẹ̀ méjìdínlógún àti àwọn alákoso tó fi mọ́ olùbádámọ̀ràn.

Ó sọ síwájú pé ìjọba rẹ̀ ńtẹpẹlẹ mọ́ ìlànà àti ààtò èyí tó lè mú kí ìpínlẹ̀ Òndó gòkè àgbà, ó wá rọ àwọn tí wọ́n yànsípò láti máse já ìlú ní tanmọ̀.

Kẹmi Ogunkọla/Dokun Ladele

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *