Yoruba

AwọnIlé-isẹ iroyin ní láti pàkíyèsí sọ́rọ áwọn arìnrìn-àjò sílè Libya – Àgbà ọjẹ̀

Lọ́nà àti wojutu soro àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tó ń gbé làwọn ilẹ̀ ókéré àti láti dènà àwọn èèyàn kúrò lọ́wọ́ bí wọ́n ṣe ń fi wọ́n sowo lairo tì, àwọn ilé isẹ igbohunsafefe gbọ́dọ̀ gunle gbígbé àwọn ìròyìn tó yẹ jáde lọ́nà àti lè jẹ́ káwọn èèyàn mọ àwọn nǹkan tó tọ́ fún wọn láti ṣe.

Èyí lafenuko àwọn tọrọ kan níbi ètò kan tonise pẹ̀lú ìròyìn latenubode, lo wáyé nilu Èkó.

Àgbà oje oniroyin kan, ọmọwe Theophilus Abbah woye pé, ojúṣe àwọn ilé – isẹ igbohunsafefe ní, láti pe àkíyèsí àgbáyé lọkan o jokan ìṣòro àtàwọn ìṣẹ̀lẹ̀ meriri tó ń ṣẹlẹ̀ sáwọn arìnrìn-àjò nílè Libya.

Fasasi/Ogunkola.

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *