Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó yóò lo owoya fáwọn isẹ ìdàgbàsókè

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó sọ pé owoya aladota bilionu náírà tilè ìgbìmò asofin Ìpínlẹ̀ òhun fowosi lose to kọjá niwọn yóò lo fáwọn isẹ ìdàgbàsókè èyí tí Gómìnà Olúwa Rotimi Akeredolu gbékalè.

Alakoso foro ìròyìn àti ila aráàlú lóye, Ogbeni Donald Ojogo lo fìdí èyí múlẹ̀ lakoko tó ń báwọn oniroyin sọ̀rọ̀ nilu Àkúré, tó sì tako aheso ọ̀rọ̀ kan pé, wọn fẹ́ lo owó náà láti tún fi gbé Gómìnà
Akeredolu padà sórí ipò àkóso.

Ogboni Ojogo tó ṣàlàyé ìdí tó fi ṣe pàtàkì kí wọ́n magbega bá àwọn ohun amayederun ńipinle náà sọ pé, owoya náà ṣe pàtàkì lọ́nà àti samulo fáwọn agbase ṣe tó wà nìdí ọkan ọjọ́ kan àwọn iṣẹ́ àkànṣe tó ń bẹ ńipinle Òndó.

Odofin/Ogunkola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *