Ìjọba
Ìpínlẹ̀ Òndó sọ pé owoya aladota bilionu náírà tilè ìgbìmò asofin Ìpínlẹ̀ òhun
fowosi lose to kọjá niwọn yóò lo fáwọn isẹ ìdàgbàsókè èyí tí Gómìnà Olúwa
Rotimi Akeredolu gbékalè.
Alakoso
foro ìròyìn àti ila aráàlú lóye, Ogbeni Donald Ojogo lo fìdí èyí múlẹ̀ lakoko
tó ń báwọn oniroyin sọ̀rọ̀ nilu Àkúré, tó sì tako aheso ọ̀rọ̀ kan pé, wọn fẹ́
lo owó náà láti tún fi gbé Gómìnà
Akeredolu padà sórí ipò àkóso.
Ogboni
Ojogo tó ṣàlàyé ìdí tó fi ṣe pàtàkì kí wọ́n magbega bá àwọn ohun amayederun
ńipinle náà sọ pé, owoya náà ṣe pàtàkì lọ́nà àti samulo fáwọn agbase ṣe tó wà
nìdí ọkan ọjọ́ kan àwọn iṣẹ́ àkànṣe tó ń bẹ ńipinle Òndó.
Odofin/Ogunkola
pub-5160901092443552