Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ lórí iná ọba

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asojú sùfin, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Gbajabiamila ti sọpé ilé yóò ripé àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì gbádùn owó tí wọ́n ńsan fún iná ọba, tí wọ́n kòsì ní fàyègba owó iná-ọba tó ńwọ àwọn aráàlu lọ́ọ̀rùn.

Adarí ilé sàlàyé pé, ilé yóò mọ́mọ̀ jíròrò lẹ́kunrẹ́rẹ́ lórí owó gọbọi táwọn ilésẹ́ apinnáká ma ń bù fáwọn oníbarà lọ́nà àti wójùtú sí ìpèníjà táwọn èèyàn ilẹ̀ yíì ńkojú.

Ọgbẹni Gbajabiamila tọ́kasi pé, ilé yóò sàtúngbéyẹ̀wò oun gbígbé òfin ọ̀tun kalẹ́ tí yóò fòpin sí bíbu owó gọbọi fáwọn oníbarà.

Lásìkò tó ńgbàlejò ìgbìmọ̀ alásẹ ilésẹ́ tó ńpín iná ọba lasìsì rẹ̀ pé ojúse ilé ni láti ridájúpé ayé rọrùn dungbe fáwọn èèyàn àwùjọ.

Kẹmi Ogunkọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *