Yoruba

Ikire: Itan bi Oruko ilu naa ti se se

Ikire lo je oruko ilu kan nipinle osun. Eniti o koko te ilu naa do ni omooba akinrere to je ode aperin lati ilu ile-ife, leni totele ase ifa pe ko mu ona ajo re pon pelu orisa toruko re nje osakire leyi to bi oruko ile ikire to tedo si.

Oniroyin ile ise Radio Nigeria, isaac haastrup be gege lowe lori itan ati eto oro aje ilu isembaye naa. 

Abo re re lati enu Gedion Aluko.

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *