Yoruba

Itan to bi Oruko ilu Jobele

Nile Yoruba ko si oruko ilu kookan ti ko ni itan tabi idi to bi oruko ilu bee. Lopo igba awon to te ilu kan do le je jagunjagun tabi alagbara. Oruko ilu bee le jeyo lati ara iru iwa ati ise awon to te ilu bee do.

  Ninu akanse iroyin yii, Akoroyin wa, Funso Aderibigbe foro wa baale ilu Jobele, Oloye Isaiah Oyerinde lenuwo nibi toti tusu desale ikoko nipa bi itan ilu Jobele se se.

Abo re ree.…

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *