Yoruba

Àjọ NBC gbé ìjìyà kalẹ̀ fún àwọn iléésẹ́ ìròyìn márùndínláadọfa

Àjọ tó ńrísọ́rọ̀ isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ NBC, ti gbé ìjìyà kalẹ̀ fáwọn ilé-isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ bí márùndínláadọta lórí ẹ̀sùn títàpà sófin àjọ náà láarin osù mkfà àkọ́kọ́ nínú ọdún yíì.

Olùdarí àgbà àjọ NBC, ọ̀gbẹ́ni Ishau Kawu tó sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì nílu Abuja, mẹ́duba diẹ lára àwọn ẹ̀sùn náà, bí síwọn àwọn ọ̀rs kòbákùngbé, ọ̀rs ebu, àtàwọn ọ̀rs min-in tí kò tọ̀nà lórí afẹ́fẹ́.

Gẹ́gẹ́ bó se wípé, lílo irúfẹ́ àwọn ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ máà ń si àwọn aráalu lọ́nà, àtàwọn tó ń se ìpolówó ọjà kòtọ́, paapa jùlọ, àwọn onísègùn ìbílẹ̀ ti le sẹ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ bí ọgbọ̀n náà sì jẹ́ fífìyà jẹ lórí irúfẹ́ ẹ̀sùn yíì.

Kẹmi Ogunkọla/Tọba Dupẹ

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *