Ìgbìms alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti fọwọ́sí billiọnu lanà ọgafà náirà ọdún kan, fún isk àkàse àwọn ojú ọ̀nà oníbejì látìlú Ìbàdàn, sí Ìlésà, Ifẹ̀, tófimọ́ Kano títídé Kastina.

Alakoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ilégbe nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla, tó sísọ lójú ọ̀rs yíì nílu Abuja, sọpé, bí ọgọ́rin biliọnu náirà odúkan látara owó náà ni wọ́n yóò ná sáwọn ojú ọ̀nà oníbejì látìlú Ìbàdàn sí Iléshà títídé ìlú Ifẹ̀.

Kò sài sọ́ọ́di mímọ̀ pe, ti sẹ́ àkànse ojú ọ̀nà Ìbàdàn sí Iléshà àti Ifẹ̀ bá parítán, yóò sọ ìpínlẹ̀ Ọyọ àtọ̀sun pọ̀mọ́rawọn.

Ọgbẹni Fashọla wá sàlàyé pé, isẹ́ àkànse ojú snà tó jẹ́ àjogúnbá látọ̀dọ̀ àwọn ìjọba tó ti rékọjá ló niwọ́n ti sọ́di tónibejì báyíì.

Kẹmi Ogunkọla/Tọba Dupẹ    

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *