Yoruba

Ìpínlẹ̀ Èkìtì bèèrè fún ìfowósowọ́pọ̀ lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti rọ àwọn ọmọbíbí ìpínlẹ̀ náà láti dásí ìgbésẹ̀ àtúntò ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ tó ńlọ lọ́wọ́ nípinlẹ̀ náà.

Igbákejì Gómìnà, Ọtunba Bisi Ẹgbẹyẹmi sọ̀rọ̀ yíì nígbà tó ńsàgbékalẹ̀ ìwé kíkà tóótó irinwó àtàwọn ohun èlò ìkẹ́kọ min-in, fún lílò àwọn akẹ́kọ lágbègbè Ìgbèmọ̀- Èkìtì.

Ọtunba Ẹgbẹyẹmi wá fikun pé, ìjọba yóò fàyègba, àwọn ilésẹ́ aládani, lájọ-lájọ láti nawọ́ sẹ́ka ètò ẹ̀kọ́ mípinlẹ̀ Èkìtì.

Kẹmi Ogunkọla/Aluko

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *