Yoruba

Ìtàn ìlú Ọtan-Ayegbaju

Ọtan Ayegbaju tó jẹ́ ibùjóko ìjọba ìbílẹ̀ Boluwaduro nípinlẹ̀ Ọsun ló kalẹ̀ sí apá àríwá ní ẹkùn Ìwó-Orùn gúsù tó sì fi Kìlómétà mẹ́tàdínlógójì jìnà sí ìlú Osogbo.

Nínú àkànse ìròyín yi, oníròyìn wa, Wasiu Ajadosu sàgbéyẹ̀wò oun tó wà lẹ́yìn orúkọ ìlú ìsẹ̀nbáyé náà.

Àtúpalẹ̀ rẹ̀ réè láti ẹnu  Serah Sanni

Otan Ayegbaju to je ibujoko Ijoba Ibile Boluwaduro nipinle Osun lo kale si apa  ariwa ni ekun iwo-orun gusu to si fi kilometer metadinlogoji jina si ilu Osogbo.

Ninu akanse iroyin yi, oniroyin wa, Wasiu Ajadosu sagbeyewo oun to wa leyin oruko, ilu isenebaye naa

Atupale re ree lati  enu Serah Sanni 

   

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *