Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀ka ìrìn àjò afẹ́

Alákoso farọ̀ ìròyìn àti àsà lórílẹ̀dè yi, Àlhájì Lai Muhamed, sọ pé láipẹ ni ìjọba àpapọ̀ yó fi ètò kan lọ́lẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àsà àti ètò ìrìnàjò afẹ́.

Àlhájì Mohamed sọ pé, ìjọba ní ìpinnu láti jẹ́ kí orílẹ̀èdè yi jẹ́ ibi tí àwọn arìnrìnàjò afẹ́ yo máà nífẹ àti wá sàbẹ̀wò si.

Alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn àti àsà na, tọ́ka si pé, àwọn ti parí isẹ́ lórí ọ̀rọ̀ àbádòfin nípa àwọn fọ́rán àgbéléwò láipẹ sí ni wọ́n ó gbe síwájú ìgbìmọ̀ alásẹ orílẹ̀èdè yí.

Kẹmi Ogunkọla

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *