Yoruba

Ijoba Apapo Jeje Amugboro Oro Aje Ipinle Osun

Ijoba Apapo orile ede yii lo nsetan lati sedasile oja nla igbalode kan tafojusunn re je tita awon nkan ire oko atokan ojokan eja nilu Ijebu-Jesa Nijoba Ibile Oriade nipinle Osun.

Alakoso foro ogbin ataabo ounje, Ogbeni Adedayo Adewale lo siso loju egun oro yii nilu Osobgbo pelu alaaye pe ile ise ijoba apapo tonrisoro okowo atidase aje sile pelu ajosepo egbe awon oloja tonrisi igbaye gbadun ere oko tita, ni yoo bere ise akanse naa.

O toka si pe ara awon abajade apero idakowo tijoba ipinle Osun sagbekale re losu kokanla odun tokoja leto na je.

Kemi Ogunkola/Adekoya

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *