Yoruba

Ijoba Apapo Salaye Ofin Lori Afikun Owo Ori Oja

Alakoso Faba Eto Isuna Atato Gbogbo Nile yi, Arabinrin Zainab Usman so pe sisamulo ekunwo owo ori oja ni yo bere lojo kini osu tonbo.

Arabinrin Usman loje keyi di mimo nilu Abuja, to si so pe gbogbo eto loti to lori igbese naa, papa otiwa ninu iwe atejade eyi ti ilese ton mojuto eto idajo ko.

Alakoso salayepe ekunwo naa toje ida marun ninu ogorun ni yo di ida meje atabo ninu ogorun ti yo si mu amugboro ba owo ti won npa wole, eyi ti won nilo lati pa alaa to wa ninu aba isuna odun 2020.

Kemi Ogunkola/Kehinde Mosope

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *