Yoruba

Ileese to Nbojuto Ibudoko Omi Jeje Atilehin Idokoowo Irorun

Lona ati mamugbooro ba igbega awon oludokowo, awon alase awon ibudoko oju omi okun to nbe nile yii, NPA, ti lawon setan lati gunle ajosepo pelu ijoba ipinle Eko.

Oludari iko alabojuto awon alase ibudoko oko oju omi okun, Arabinrin Hadiza Usman lo soro yii di momo nilu Eko, mu dajoba ipinle naa loju pe NPA yoo sise papo pelu awon torokan lati mu keto idokoowo rorun lawon ibudoko oju omi.

Ko sai soodi mimo pe ile ise naa yoo ko akoyawo ninu gbogbo awon akitiyan re lawon ibudoko naa nibanu pelu bofin selakale.

Ninu oro tie, Olubadamoran Pataki si Gomina Ipinle Eko Lori Oro Idokowo, Ogbeni Olanrewaju Elegushi jeje atileyin ijoba ipinle Eko fawon alase ibudoko oko oju omi okun lati mu kerongba re wa si imuse.

Ogunkola/Famakin

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *