Àgbà Amofin kan lorileèdè yi, Oloye Afe Babalola, ṢAN, ti ṣàlàyé pé, bí ìjọba Àpapọ̀ bá gbìyànjú láti denáà.

Iko eleto ààbò tapa iwoorun ilẹ̀ Nàìjíríà fi lólè èyí tí wọ́n pè ní Àmọ̀tẹ́kùn, Igbìyànjú nà, kò lè bó sii, torí pé, ìwé òfin orílèèdè yi ko tako àgbékalè iko eleto ààbò nà.

Oloye Babalola sọ pé àwọn tó ń tako iko Àmọ̀tẹ́kùn nà, kò mọ ohun tó wà nínú ìwé òfin orílèèdè yi ni. 

Ó ní ohun tí agbfoba àgbà lorileèdè yi, tí í tún ṣe Alákoso feto idajọ, Abubakar Malami sọ kudie káà tó, torípé abala kerinlelogun abala ogójì, àti abala Kàrúnlèlogoji nínú ìwé òfin todùn 1999, sọ pé àwọn aráàlú lójúṣe láti rí dájú pé, wón ní ààbò tó tó fún ẹ̀mí àti dúkìá wọn.

Ogunjola/Famakin

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *