Àjò ton mojuto ìdánwò síle ẹ̀kọ́ gíga vasiti nílè yíì JAMB tí gba ìwé àṣẹ ibùdó mọ́kànlá tí wọ́n ti ń ṣe ìdánwò náà padà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n gba owó lọ́wọ́ àwọn akẹ́ko lórí iforukosile to lọ lọ́wọ́ fún ìdánwò.

Ogagba àjọ òhún, Ojogbon Ishaq Oloyede ló sọ èyí di mímọ, lásìkò ifikùnlukùn pẹ̀lú àwọn torokan nilu Abuja.

Oní oje on ton konilominu pẹ̀lú bí oniruru Ibùdó ìdánileko JAMB, sen posi, àti wípé òpò nínú wọn ni wọ́n ń lu akẹ́ko ní jìbìtì lásìkò tí wọn bá fé fi orúkọ sílè.

Ojogbon Oloyede tókasi pé gbigba owó tọju ẹgbẹ̀rún márùn-ún Odin ọdún rùn náírà lọ lọ́wọ́ akẹ́ko tó fẹ́ forúkọ sílè ni oje èyí tí kò bojumu tosile ta ere àbùkù lé ilẹ̀ yí.

Kẹmi Ògunkọla/Rotimi Famakin

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *