Ìjọba Àpapọ̀ tí ni ìpàdé alágbára ti ń lọ lọ́wọ́ lórí àti ṣàgbékale ìlànà ìgbìmò àti ìgbìmò tí wọ́n yio fi máa bójútó dènà àti ọ̀nà tí wọ́n fi lè tẹle keefin bí àrùn Corona bá fẹ́ rapala wọlé sórílè èdè yìí.

Alákoso foro ìlera, Dókítà Osagie Ehanire ẹnití ó ní àwọn pápákò  òfuurufú sanko sanko márùn-ún tó wà nílè yíì ni àwọn yio gbajumo soro yi nilu Abuja níbi ìpàdé oniroyin kan tó da lori itaniji ará ìlú àti pípe àkíyèsí àwọn ènìyàn soro ìlera.

Ó ní ìgbìmò náà ni àwọn tọrọ kan gbongbon leka ètò ìlera, ààbò ìrìn àjò ọkọ̀ òfuurufú àti ẹ̀ka ìgbòkègbodò ọkọ̀ yio wà nínú rẹ̀.

Dókítà Ehanire ṣàlàyé wípé àwọn tó ń rìnrìn àjò láti pèsè ọkọ̀ òfuurufú àti àwọn tó ń gba ẹnu bode wọlé ló seese kí wọ́n ní kòkòrò àrùn yi.

Ó wà tẹnumó wípé àkíyèsí àwọn yio wà làwọn pápákò òfuurufú fún ìrìn àjò sílè òkèèrè nílè yíì.

Ogunkola /Famakin 

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *