Yoruba

Igbimo to n risi awuyewuye lasiko idibo pase eto idibo miran n’ipinle Bayelsa

Loni, igbimo ton risi awuyewuye to suyo lasiko idibo ni won fagile eto idibo to gbe Gomina Douye Diri ati igbakeji Gomina Lawrence Ewhtujakpo wole.

Nine idajo eyi ti Adajo Yunusa Musa gbe kale, sope iwe edun eyi ti egbe osele Advance National Democratic Party, ANDP ko eyi to fihan pe Ajo to n mojuto eto idibo nile yi INEC, lo ti yo oruko egbe oselu naa kuro, ninu awon to kopa ninu eto idibo lojo kerindinlogun, osun kokanla odun 2019.

Igbimo to n risi awuyewuye to suyo lasiko idibo, wa pa laase pe ki ajo INEC seto idobo sipo Gomina miran nipinle Bayelsa larin adorun ojo. Lolade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *