News Yoruba

Olósèlú kan gba ìjọba àpapọ̀ nímọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ epo àtafẹ́fẹ́ gési

Wọ́n ti gba ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀èdè yíì nímọ̀ràn lati tún ìpinnu rẹ̀ se lórí ọ̀rọ̀ epo àtẹfẹ́fẹ́ gási láti mádinkùn bá ìsoro táráàlu ńkojú látara rẹ̀.

Olórí àwọn òsìsẹ́ fún Gómìnà tẹ́lẹ̀ nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ológbe Abiọla Ajimobi, ọ̀mọ̀wé Gbade Ojo, ló gbọrọ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀ lákokò tón kópa lórí ètò ilé-isẹ́ wa kan lédè gẹ́ẹ̀si tapeni the stage nìkànì Premier F.M 93.5

Ọmọwe Ojo tẹnumọ pé, bíjọba se àtúnse ìlànà lẹ́ka epo rọ̀bì àtẹfẹ́fẹ́, gáàsi loni yóò túbọ̀ fikún ìnira táráàlú ńkojú látara rẹ̀.

Kò sái tọ́kasi pé, ó se pàtàkì fúnjọba àpapọ̀ láti mátunse tó lóòrin bẹ́kaètò ọ̀gbìn nípasẹ̀ kíkọ́ àwọn ibùdó àkankan pamọ́sí lọ́pọ̀si, nílẹ̀ yíì gẹ́gẹ́ bó se ní èyí yóò tún sèrànlọ́wọ́ fáwọn àgbẹ̀ tón bẹ lórílẹ̀dè yíì.

Ọmọwe Ojo tí tún se, onímọ̀ nípa ọ̀rọ̀ òsèlú rọ ìjọba ni gbogbo ẹ̀ka láti mádinkùn bá owó yíyá wọn, dípò bẹ́ẹ̀ kíwọ́n túbọ̀ tẹpẹlẹ mọ́ àwọn ọ̀nà tíwọ́n yóò fi túbọ̀ máà rówó pa wọlé lábklé si.

Wojuade  

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *