Bí orílẹ̀èdè Nàijírìa yóò báà lọ́wọ́ ìpènìjà tó ńkojú, ẹ̀ka ètò àbò rẹ̀, àwọn lọ́ba-lọ́ba gbọ́dọ̀ jẹ́ fífún ni ojúse níbamu pẹ̀lú òfin orílẹ̀èdè yíì.

Èyí jẹ́ àfẹnukòadarí ilé-ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, Amad Lawan níbi ìpàdé kan tówà yẹ́ẹ̀ lófìsì rẹ̀ nílu Abuja.

Adarí ilé sàlàyé pé, fífún àwọn lọ́ba-lọ́ba lójuse yóò sèrànwọ́ fún ìjọba àtàwọn àjọ elétò àbò láti wójùtú sí ìpèníjà ètò àbò.

Ó tọ́kasi pé, àwọn lọ́ba-lọ́ba ma ń sátìlẹ́yìn fún ìjọba tó sì rọ̀ wọ́n pé kíwọ́n máàse káàrẹ nídi fífa rere àláfìa.

Mnt/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *