Yoruba

Awon Adije Ninu Eto Idibo Ipinle Ondo Towobo Iwe Adehun Alaafia.

Awon adije ninu eto idibo Gomina ti yio waye nipinle Ondo ti towo bo iwe adehun alaafia lati lee ri wipe ofan o firu nagba lasiko eto idibo .

Lara awon to towobo ise adehun ti igbimo apapo lori alaafia sagbateru re lati ri adije ninu egbe oselu All Progressiives Congreee, APC,, Gomina Rotimi Akeredolu ti egbe oselu Peoples Democratic Party, PDP, Eyitayo Jegede, ti Zenith Labour Party, ZLP, tii tun se igbakeji Akeredolu, Ogbeni Agboola Ajayi ati awon metala min.

Nibi eto bibuwolu iwe adehun yi ni ati ri alaga apapo fun ajo eleto idibo ileyi, Ojogbon Yakabu Mahmood, Sultan tilu Sokoto, Abubakar Saa’d, Bishop ekun Sokoto, Hassan Kukah ati Bishop, ti Abuja tete John Onaiyekan ati awon oba Alaye.

 Net/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *