News Yoruba

Egbe Awon Odo Pe Fun Igbese To Gbopon Fi Wojutu Si Ipenija Ainiselowo

Egbe awon odo nile yi NYCN eka tipinle Oyo ti kesi ijoba ati tipinle, lati wa n kan sesi bii ainiselowo se gogo larin awon odo orileede yi.

Alaga egbe NYCN, Arabinrin Adebobola Agbeja enito soro yi lasiko to nba awon oniroyin soro nilu Ibadan sope awon odo tootoo million meji niko nise lowo eyito npe fun amojuto latodo ijoba.

Nigba to nsoro fun ayajo awon odo nile Africa, fun todun yii, pelu akori, ohun awon odo, igbese lilowo lati mu ile africa dara sii, Arabinrin Agbeja ro awon alase torokan lati dehin nidi awon liana ati eto tiko sanfani fawon odo.

Bakanna lotun rawo ebe sijoba lati faaye gba awon odo feto adari.

 kehinde/idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *