Ìjọba àpapọ̀ sọ pé òun yo tẹpẹlẹ píparí àwọn isẹ́ àkànse ojú òpópónà àti afárá tón lọ lọ́wọ́ nílẹ̀ Nìajírìa dípò bíbẹ̀rẹ̀ isẹ́ àkànse tuntun, nínú sísàmúlò àbá ìsúná fún tọdún 2021.

Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ilégbe, ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla tó sọ̀rọ̀ yí nílu Abuja, tọ́kasi pé, irúfẹ́ àwọn isẹ́ àkànse òpópónà tójẹ́ méjìdínlógún níye, ni óti fẹ́ parí kótó di àpatì yíká ill yí, ni wọ́n yo parí lárin osù méjìlá sí mẹ́dogún.

Alákoso se lálàyé pé ìgbésẹ̀ ìsè jọba Muhammadu Buhari ni láti náà owó ọ̀hún lórí píparí àwọn isẹ́ àkànse.

Ọgbẹni Fashọla fikun pé, afárá tó jẹ́ àdọ́ta níye ni wọ́n yo túnse yíká orílẹ̀èdè Nìajírìa.

Ọlọlade Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *