Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, ọ̀gbẹ́ni Godwin Obaseki ti ké sílesẹ́ ọlọ́pa ìpínlẹ̀ náà látiridájú pé, àwọn sàwárí gbogbo àwọn ẹlẹ́wọn tí wọ́n sákúrò níbùdó àtúnse tó wà ní Okoh àti Sapele lákokò ìfẹ̀húnúhàn fífòpinsí ikọ̀ Sars, kíwọn sì mú gbogbo wọn.

Gómìnà Obaseki ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yí lákokò ikẹ́kọ́ọ̀ jáde àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ ọlọ́pa lábẹ́ ìlànà ètò ọlọ́pa agbègbè tó wáyé nílé ẹ̀kọ́ àwọn ọlọ́pa nílu Benin.

Ó sàlàyé pé, àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ ọlọ́pa náà yóò máà sèrànlọ́wọ́ fúnlesẹ́ ọlọ́pa nídi isẹ́ ọlọ́pa agbègbè.

Gómìnà Obaseki kò sài fikun pé, ìjọba ìpínlẹ̀ náà yóò tẹ̀síwájú nídi ètò ìdánilẹ́kọ fáwọn òsìsẹ́ aláàbo lọ́dọọdún lọ́nà àti jẹ́kí wọ́n máà jáfáfá si lẹ́nusẹ́ tíwọ́n yàn lọ́àyo àti faabo ẹ̀mí àwọn èeyàn ìpínlẹ̀ náà.

Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *