Yoruba

Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ buwọ́lu àbá ètò ìsúná ọdún 2021

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti so àbá ètò ìsúná ọdún 2021 tí iye rẹ̀ jẹ́ ọ̀ọdúnrún ófín diẹ billiọnu naira.

Èyí ló wáyé níbamu pẹ̀lú àbọ̀ tígbìmọ̀ tẹkótó ilé fọ́rọ̀ tóníse pẹ̀lú àsùnwọ̀n owólu, ètò ìsúná àtàatò gbogbo gbékawájú ilé lákokò ìjóko rẹ̀.

A ó rántí pé, ní ǹkan bí ọ̀sẹ̀ diẹ sẹ́yìn, ni Gómìnà Seyi Makinde ti dába iye owó tíwọ́n ńgbà lérò láti gbékalẹ̀ fába ètò ìsúná ọ̀hún fọ́dún 2021, tó jẹ́ ọ̀ọdúnrún dín mẹ́rìnlẹ̀lọ́gbọ̀n billiọnu naira èyí tílé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ wá sàtúngbéyẹ̀wò rẹ̀ sí ọọdunrun dín diẹ billiọnu naira.

Kehinde/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *