Aare Muhammadu Buhari, igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo atawon eekan nile yii, ti setan lati waa lara awon ipe akoko awon eeyan ile yi ti yoo tha abere ajesara covid-19.

Oludari ajo apapo to nrisi idagbasoke eto ilera, NPHCDA, Dokital Faisal Shuaib soro yi nilu Abuja nibi abo ise iko amuseya ijoba apapo farun covid-19.

O salaye pe, orileede yi ti pinu lati gba abere ajesara covid-19, million mejilelogoji fawon ida kan ninu maarun awon eeyan ile yii labe liana abo covax lagbaye.

Dokital Shuaib tokasi pe liana covas naa loja gbigbekale lati pese abere ajesara fawon orileede to se se n didele, nibiti awon tootoo million ona igba ati eto igbayegbadun to mehe tin je ipenija fawon osise eleto ilera to nseto abere ajesara ohun.

Ko sai wa ro awon eeyan ile yi lati mase kaare nidi gbigba abere ajesara covid-19 ket toba ti de orileede yi.

Idogbe/Net

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *