Ọ̀rọ̀ kí a máa ṣe ìdájọ́ ojú ẹsẹ̀ fún ẹni tí a bá fi ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn kàn,èyí tí àwọn olọ́yìnbó n pè ní “Jungle Justice” ti di ohun tó fẹ́ jẹ́ pé ojoojúmọ́ ló n wáyé, lénu ọjọ́ mẹ́ta yi.
Kínni ewu tó rọ̀mó ìwà yí àti pé kínni àtúbọ̀tán rẹ ló rí àwùjọ lápapọ̀?
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àkànṣe ìròyìn náà rèé lẹ́nu Afọlásadẹ́ Òsigwè.
Afọlásadẹ́ Òsigwè