Yoruba

Igbakeji Aare Osinbajo So Pataki Anfani To Ro Mo Olopa Agbegbe

Igbakeji Aare lorile ede yi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti se koriya fawon ijoba ipinle lati tesiwaju ninu eto ekoni latifese eso aabo mule lagbegbe won, lona ti won yo fi gba kin teko ijoba apapo leyin.

O soro yi lasiko ti won n seto lati foruko sile awon omo egbe oselu All Progressive Congress APC, nijoba ibile Ikenne nipinle ogun.

Igbakeji Aare, Osinbajo, eni to tenumo idi to fi ye kanugboro deba ise olopa lagbegbe fi owo idaniloju soya pea won loga-loga tuntun ni won yo gbe igbese otun lati fi opin si igbesunmomi lekun ila oorun ariwa ile yi, to fimo fifi opin is iwa ijinigbe ati rogbodiyan to n sele lawon apa ibikan nile yi.

Ojogbon Osinbajo sope eto fifi oruko sile awon omo egbe, lo ni anfani lati sise papo pelu awon omo egbe, to wa ni wardu, Ijoba ibile to fimo leka ijoba apapo.

O tesiwaju ninu oro re pe, botilejepe ile Naijiria n koju okan o jokan ipenija sibe isejoba eyi ti egbe oselu APC luko re, nsise kara-kara lati wojutu sawon ipenija wonyi.

Ojogbon Osinbajo tokasi pe yato fun okanojokan eto tonise pelu ironilagbara ati ise fun eyan to few o million kan.

Ijoba apapo ti se ifilole, eto kiko ilegbe, eto ogbin lopoyanturu to fimo lilo itansan oorun fun ina, lawon ile to wo million marun niye.

Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *