Ijoba ipinle Ogun yoo ri daju pe won pese gbogbo ohun elo to ye fun ipale idoti mo jakejado ipinle  naa pelu bi awon musulumi se n sayeye odun ileya.

Oludamoran Pataki fun Gomina lori oro ayika, eni ti o tun se oga agba ajo to n pale egbin mo nipinle naa (OGWAMA) Ogbeni Ola Oresanya lo seleri yi ninu atejade to fi sita nilu Abeokuta.

Ogbeni Oresanya salaye wipe akanse eto ipale egbin mo yoo waye lati fi ri daju pe ipinle na n wa ni mimo lasiko ayeye odun ileya wipe lilo oun wlo igbaloke atawon ti yoo maa gba ile.

O wa gba awon araalu ati alejo to ba wa si ipinle naa lasiko odun ninu eran pe kin rii daju pe won n pale idoti ti won ba lo mo, Pataki julo idoti to ba waye lati ara eran tabi adiye ti won ba pa.

Oludamoran Pataki fun Gomina ipinle Ogun lori oro ayika tun to awon awako pe ki won maa feso se nipa titese ofin ati liana oju popo ati pea won osise oro ayika naa yoo wa lenu ise ni gbogbo akoko odun.

        Oluokun/Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *