Yoruba

Gomina Ipinle Oyo Kedun Lori Ipapoda Giwa Ile Ise Fresh Fm, Ado Ekiti

Gomina ipinle oyo onimo ero seyi makinde ti so wipe iku giwa ile ise fresh fm ado ekiti ogbeni David Ajibore ba oun leyafu.

Afejade latodo oluranlowo pataki si gomina lori oro iwe iroyin , ogbeni Moses Alao sapejuwe iku ojiji to wa gbaa ladura ki olorun tu alaga ile ise fresh fm sile, ki o si fun won loore ofe ati gba isele naa more.

Gomina tun gbadura ki olorun te ogbeni david ajiboye si afefe rere.

Adebisi/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *