Yoruba

Onimo Nipa Esin Islam, Pe Fun Ayipada Iwo Laarin Awon Omo Ile Yi, Lori Ifara Eniji

Onimo nipa esin islam Sheikh Muyeedeen ayede ti so pe, ninu ayipada ikan awon eyan orileede yi, se pataki fun kile yi le  tunbo dara .

O soro yi nilu Ibadan lasiko iwode lati samin odun hijrah, ti se osun tuntun awamusulumi lagbaye 1443 eyi ti igbimo awon odo musulumi nacomyo teka  ipinle oyo se agbateru

Sheikh ayede tenumo idi pataki to fi ye ki awon eeyan ile yi , ni ayipada okan nipa ile niajiria ki won wo je ki gbogbo  nkan  to je  oro agbega ile yi mumu lokan won.

Alaga nibi  eto naa, titun se igbakeji are lekun gusu, fun ajo ton mojuto oro esin islam nile  naijiria

Alhaji Rasaki Oladejo ro awon musulumi lati mu ki pataki hijrah han ninu igbe aye won lojojumo.

Fasasi/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *