Yoruba

Aare Buhari Gboju Agan Sawon To N Dun Kukulaja Mo Alaafia Ile Nigeria

Lojuna ati fopin si awon lasigbo ati iwa odaran nileyi isejoba Aare Muhammadu Buhari ti sope oun yoo nawogan oun gbigbe rele ejo awon to nda wahala sile nileyi.

Aare Buhari soro naa ninu ibanisoro re fun ti isamin ayajo odun kokanlelogota tile Nigeria ti gba ominira.

Nigba to nro awon omo ile yi lati gba alaafia ohun ifikunlukun laaye, Aare Buhari sope alaafia yoo joba tawon eeyan ile yi bale maa gbe gege bi eyokan.

Bakan naa laare tun ro awon agbohunsafefe lati jina si sise agbejade nkan ti o tona pelu gigunle sise ise iwadi ninu agbejade iroyin.

Liri fifofinde ikanni abeyefo twitter, nibere odun yi,  Aare Buhari sope liana aateele ti w anile lori lilo pada ate ohun peu riro awon eeyan ile lati samulo ate ayilujara bose to.

Aare to sai je ko di mimo pe idagbasoke ile Nigeria lo nile agbajo owo taafi soya kise ise ijoba nikan.

Blessing Adesanya/Ayodele Olaopa

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *