Gomina ipinle Oyo, Onimo Ero Seyi Makinde ti kesi oga agba ajo otelemuye tuntun nipinle Oyo lati seranwo lori sise iwadi nkan to fa ti fo agba stunse Abolongo nilu Oyo.

Gomina Makinde soro naa lasiko to n gbalejo Oga Agba ajo Otelemuye Ipinle Oyo tuntun, Ogbeni Agada Ales lofisi te towa ni Sekiteriat Agodi Ibadan.

O salaye pe o se Pataki kajo naa seranwo lori titu fin idi koko fun okunfa fifo ogba ewon ohun kole dekun irufe isele bee lojo iwaju.

Gomina Makinde salaye pe isejoba re yoo maa tesiwaju lori sise ikunlowo fajo otelemuye atawon eso alaabo to ku nipinle yi.

Saaju ninu oro Oga agba ajo otelemuye tuntun naa nipinle yi, Ogbeni Agada Alex, lo ti famin idaniloju han si Gomina pe ajo naa yoo maa te siwaju lori sisopa re lori eto abo ipinle yi ko le wa ni ipo awokose re.

Ayodele Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *