Yoruba

Àjọ NIMET Sèkìlọ̀ Fáwọn Àgbẹ̀ Lórí Àmúlò Ìròyìn Àyípadà Ojú ọjọ

Ajo ton risi oro ayipada oju ojo nileyi, NIMET ti kesi awon eni orokan leka eto ogbin nipinle ogun lori lilo anfani awon ikede ajo naa lori boju ojo seleri fun eto ogbin ohun ise agbe lapapo.

Eekan awosakun oju ojo lati ajo ohun, Ogbeni Charles Olubiyi lo soro iyanju naa nilu abeokuta lasiko eto idanileko olojo kan fawon eni-orokan leka ise agbe lori igbelaruge eto iroyin to ro mo tayipada oju ojo fawon agbe.

Ogbeni Olubiyi sope,o se pataki lati jeki awon agbe mo pataki iroyin lori ayipada oju ojo kole seranlowo fun iragogo ipese ounje.

O wa je ko di mimo pe nipase iwosakun oju ojo latodo ajo NIMET,sise ise po pelu awon agbe,eto ipese nkan ti yi pada,pelu alaye pe aisiroyin to poju owo lori ayipada oju ojo lateyin wa ti sepalara fawon agbe.

Tawakalit Ibrahim/Ayodele Olaopa

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *