Home Articles posted by Web News (Page 548)
Security

Ogun Govt. take steps to bolster Security

Ogun State Government has concluded arrangements to install Close Circuit Television, CCTV, at strategic locations across the State. Special Adviser to the Governor on Security, Retired AIG Olusola Subair made this known While playing host to the National Economic Council Implementation Committee team in his Office in Abeokuta Retired AIG Subair who pointed Continue Reading
Education

NECO Releases 2020 SSCE Results

National Examination Council, NECO, has announced the result of candidates that sat for 2020 Senior School Certificate Examination, SSCE.  Reacting to the development the principal, Ibadan Boys High School, Dr. Rasheed Fasasi, during an interview with Radio Nigeria, said his school was yet to receive the details of the candidates’ results. Also, some candidate in […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn sísanwó osù tuntun fòsìsẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti tọwọ́bọ ìwé padéhùn àfẹnukò kan lórí sísanwó osù tuntun fáwọn òsìsẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó jẹ́ tìpínlẹ̀ yíì. Ilé isẹ́ ètò ẹ̀kọ́ ìpínlẹ̀ yíì tó wà ládugbò Agodi secretariat ìbàdàn niwọ́n ti tọwọ́ àdéhùn náà. Níbi ètò náà, lalákoso fétò ẹ̀kọ́, ọ̀gbẹ́ni Ọlasunkanmi Ọlalẹyẹ ti sọ́ọ̀di mímọ̀ pé, àfẹnukò náà ló […]Continue Reading
Yoruba

Bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, CBN, sàgbékalẹ̀ ìlànà ẹ̀rọ atètè dánhun sọ̀rọ̀ owó sísan

Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ ilẹ̀ yíì CBN, ti sí sísọ lójú ìlànà ẹ̀rọ ìsanwó kan èyí tíwọ́n yóò tètè máà dánhun sáwọn ọ̀rọ̀ tóníse pẹ̀lú owó sísan léyi tí yóò lọ́wọ́ àwọn tón gbéjáde àtàwọn olùkópa min-in lórílẹ̀dè yíì látiridájú pé wọ́n ń sàmúlò ìlànà ọ̀hún. Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ náà sọ́ọ̀di mímọ̀ pé, àwọn ìlànà ọ̀hún […]Continue Reading
Yoruba

Aláṣẹ Ilé Ẹ̀kọ́ Poly Ìbàdàn Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò Láti Yanjú Ìyansẹ́lódì

Àwọn aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ gbogbonise Ìbàdàn tí bẹ̀rẹ̀ síní jiroro pẹ̀lú àwọn ádárì ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ilé ẹ̀kọ́ náà pẹ̀lú ìrètí láti tètè yanjú ìyansẹ́lódì tó ń lọ lọ́wọ́. Níbi ìpàdé tí Alága Ìgbìmò Aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Kúnlé Akínyemí darí ni àwọn ọmọ ìgbìmò mẹ́tèeta yoku pé ṣe si àti àwọn aláṣẹ ilé […]Continue Reading