-
Ijoba Apapo Ṣèlérí Titepele Mo Didari Ọrọ Ajé Gba Ibòmíràn
Igbakeji aare , ojogbon Yemi Osinbajo ti fi ireti han wipe orile ede Naijiria losi wa loju ona toto lori didari oro aje gba ibomiran nipa tenpele mo awon oja ti won nko lo ile okeere ti ko ni nknakan se pelu epo robi eyiyi ajo tonrisi oro kiko oja lo ile okeere nile yi…