Ijoba ipinle osun ti tẹwọgba abẹrẹ ajẹsara lati dena itankalẹ arun COVID-19 toto fun eyan to le ni ẹgbẹrun mẹta din ladọta, latọdọ ijọba apapọ. Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ọsun, Ọgbẹni Benedict Alabi, lo jẹ kọrọ naa di mimọ, l’asiko iside, gbigba abẹrẹ ajẹsara ohun lelekeji nilu Osogbo. Ọgbẹni Alabi Continue Reading