Home Posts tagged Adarí ilé ìgbìmọ̀ asojú sùfin
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ lórí iná ọba

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asojú sùfin, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Gbajabiamila ti sọpé ilé yóò ripé àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì gbádùn owó tí wọ́n ńsan fún iná ọba, tí wọ́n kòsì ní fàyègba owó iná-ọba tó ńwọ àwọn aráàlu lọ́ọ̀rùn. Adarí ilé sàlàyé pé, ilé yóò mọ́mọ̀ jíròrò lẹ́kunrẹ́rẹ́ lórí owó gọbọi táwọn ilésẹ́ apinnáká Continue Reading