Home Posts tagged Àjọ INEC
Yoruba

Àjọ INEC sún ètò àtúndì ìbò yíká orílẹ̀èdè yíì síwájú

  Àjọ elétò ìdìbò nílẹ̀ yíì, INEC, ti sún ètò àtúndì ìdìbò tóyẹ kówáyé lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù yíì, láwọn ìpínlẹ̀ mọ́kànlá nílẹ̀ yíì síwájú.  Alákoso àti alága fọ́rọ̀ ìròyìn àti ìgbìmọ̀ ìlanilọ́ọ̀yẹ̀ àwọn olùdìbò, ọ̀gbẹ́ni Festus Okoye, ẹnitó tó sọ̀rọ̀ yíì nílu Abuja, sọpé àjọ náà gbé Continue Reading
Yoruba

Àjọ INEC fọkàn àwọn ẹgbẹ́ òsèlú kan balẹ̀ lórí ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná tó wáyé

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yí, INEC, ti ní ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá iná tó wáyé lápá ibìkan nílé isẹ́ nà tó wà nílu Àkúrẹ́ kò ní nípa lórí ètò ìdìbò Gómìnà tí yio wáyé ní ọjọ́ kẹwa osù tó ńbọ̀ nípinll Òndó. Alága ẹ̀ka tó wà fún ìdánilẹ̀kọ olùdìbò nínú àjọ ọ̀ún, ọ̀gbẹ́ni Festus Okoye ló sọ̀rọ̀ […]Continue Reading