-
Ajo Isokan Ile Europe Kede Atileyin Forilede Nigera Lati Gbogun ti Igbesunmomi
Ajo Isokan Ile Europe ti sofun ijoba apapo wipe gbigbogunti igbesunmomi, laapaa ariwa ila oorun ati awon ipenija leka abo jakedado ile yii, koja fifi awon omo ogun sowo sawon agbegbe ti ipenija waye. Nigba to nba awon oniroyin soro, saaju ayeye ojo Europe fun todun yii, olori iko ile europu sorilede Nigerai, ati ajo…