Home Posts tagged Àjọ tón rí sétò ìkànìyàn
Yoruba

Àjọ tón rí sétò ìkànìyàn gbé ìgbésẹ̀ sáàjú ètò ìkànìyàn ọdún 2021

Àjọ tó ń rí sétò ìkànìyàn nílẹ̀ yíì ti gùnlé ètò ìlanilọ́yẹ̀ fáwọn èèyàn tó wà lẹ́kùn ìjọba ìbílẹ̀ gúsù Ogbomọshọ àti Surulere nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, lórí ètò ìkànìyàn fún tọdún 2021, láwọn agbègbè tó wà lẹ́nu àlaà[. Ẹnìkan tétò náà sojú ẹ̀, láwọn ìjọba ìbílẹ̀ méjèejì, ọ̀gbẹ́ni Adedayẹ Adelọwọ, sọ pé Continue Reading